Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 15:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si dé Elimu, nibiti kanga omi mejila gbé wà, ati ãdọrin ọpẹ: nwọn si dó si ìha omi wọnni nibẹ̀.

Ka pipe ipin Eks 15

Wo Eks 15:27 ni o tọ