Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 15:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni Mose mú Israeli jade lati Okun Pupa wá, nwọn si jade lọ si ijù Ṣuri; nwọn si lọ ni ìrin ijọ́ mẹta ni ijù na, nwọn kò si ri omi.

Ka pipe ipin Eks 15

Wo Eks 15:22 ni o tọ