Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 13:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe nigbati OLUWA yio mú ọ dé ilẹ awọn ara Kenaani, ati ti awọn enia Hitti, ati ti awọn ara Amori, ati awọn Hifi, ati awọn Jebusi, ti o ti bura fun awọn baba rẹ lati fi fun ọ, ilẹ ti nṣàn fun warà ati fun oyin, on ni iwọ o ma sìn ìsin yi li oṣù yi.

Ka pipe ipin Eks 13

Wo Eks 13:5 ni o tọ