Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 13:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si wi fun awọn enia na pe, Ẹ ranti ọjọ́ oni, ninu eyiti ẹnyin jade kuro ni Egipti, kuro li oko-ẹrú; nitori ọwọ́ agbara li OLUWA fi mú nyin jade kuro nihin: a ki yio si jẹ àkara wiwu.

Ka pipe ipin Eks 13

Wo Eks 13:3 ni o tọ