Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 13:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si nlọ niwaju wọn, ninu ọwọ̀n awọsanma li ọsán, lati ma ṣe amọna fun wọn; ati li oru li ọwọ̀n iná lati ma fi imọlẹ fun wọn; lati ma rìn li ọsán ati li oru.

Ka pipe ipin Eks 13

Wo Eks 13:21 ni o tọ