Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 13:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si gbé egungun Josefu lọ pẹlu rẹ̀; nitori ibura lile li o mu awọn ọmọ Israeli bu pe, Lõtọ li Ọlọrun yio bẹ̀ nyin wò; ki ẹnyin ki o si rù egungun mi lọ pẹlu nyin kuro nihin.

Ka pipe ipin Eks 13

Wo Eks 13:19 ni o tọ