Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 12:48 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati alejò kan ba nṣe atipo lọdọ rẹ, ti o si nṣe ajọ irekọja si OLUWA, ki a kọ gbogbo ọkunrin rẹ̀ nilà, nigbana ni ki ẹ jẹ ki o sunmọtosi, ki o si ṣe e; on o si dabi ẹniti a bi ni ilẹ na: nitoriti kò si ẹni alaikọlà ti yio jẹ ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin Eks 12

Wo Eks 12:48 ni o tọ