Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 12:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹ wipe, Ẹbọ irekọja OLUWA ni, ẹniti o rekọja ile awọn ọmọ Israeli ni Egipti, nigbati o kọlù awọn ara Egipti, ti o si dá ile wa si. Awọn enia si tẹriba nwọn si sìn.

Ka pipe ipin Eks 12

Wo Eks 12:27 ni o tọ