Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 10:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn iranṣẹ Farao si wi fun u pe, ọkunrin yi yio ti ṣe ikẹkùn si wa pẹ to? jẹ ki awọn ọkunrin na ki o lọ, ki nwọn ki o le sìn OLUWA Ọlọrun wọn: iwọ kò ti imọ̀ pe Egipti run tán?

Ka pipe ipin Eks 10

Wo Eks 10:7 ni o tọ