Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 10:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose ati Aaroni si wọle tọ̀ Farao lọ, nwọn si wi fun u pe, Bayi li OLUWA Ọlọrun Heberu wi, Iwọ o ti kọ̀ pẹ tó lati rẹ̀ ara rẹ silẹ niwaju mi? jẹ ki awọn enia mi ki o lọ, ki nwọn ki o le sìn mi.

Ka pipe ipin Eks 10

Wo Eks 10:3 ni o tọ