Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 10:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Farao si wi fun u pe, Kuro lọdọ mi, ma ṣọ́ ara rẹ, máṣe tun ri oju mi mọ́; nitori ni ijọ́ na ti iwọ ba ri oju mi iwọ o kú.

Ka pipe ipin Eks 10

Wo Eks 10:28 ni o tọ