Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 10:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si wi fun Mose pe, Nà ọwọ́ rẹ si ọrun, ki òkunkun ki o ṣú yiká ilẹ Egipti, ani òkunkun ti a le fọwọbà.

Ka pipe ipin Eks 10

Wo Eks 10:21 ni o tọ