Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 10:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si nà ọpá rẹ̀ si ori ilẹ Egipti, OLUWA si mu afẹfẹ ìla-õrùn kan fẹ́ si ori ilẹ na, ni gbogbo ọsán na, ati gbogbo oru na; nigbati o di owurọ̀, afẹfẹ ila-õrùn mú awọn eṣú na wá.

Ka pipe ipin Eks 10

Wo Eks 10:13 ni o tọ