Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹk. Jer 4:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ti o ti njẹ ohun didùndidùn nkú lọ ni ita: awọn ti a ti tọ́ ninu aṣọ-òdodó, gbá ãtàn mọra.

Ka pipe ipin Ẹk. Jer 4

Wo Ẹk. Jer 4:5 ni o tọ