Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹk. Jer 3:19-22 Yorùbá Bibeli (YCE)

19. Ranti wahala mi ati inilara mi, ani ìkoro ati orõro.

20. Lõtọ, nigbati ọkàn mi nṣe iranti wọn, o si tẹriba ninu mi.

21. Eyi ni emi o rò li ọkàn mi, nitorina emi o ma reti.

22. Ãnu Oluwa ni, ti awa kò parun tan, nitori irọnu-ãnu rẹ kò li opin.

Ka pipe ipin Ẹk. Jer 3