Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹk. Jer 2:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ti wó ọgba rẹ̀ lulẹ, gẹgẹ bi àgbala: o ti pa ibi apejọ rẹ̀ run: Oluwa ti mu ki a gbagbe ajọ-mimọ́ ati ọjọ isimi ni Sioni, o ti fi ẹ̀gan kọ̀ ọba ati alufa silẹ ninu ikannu ibinu rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹk. Jer 2

Wo Ẹk. Jer 2:6 ni o tọ