Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹk. Jer 2:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn ti nkọja patẹwọ le ọ; nwọn nṣẹsin, nwọn si nmì ori wọn si ọmọbinrin Jerusalemu; pe, Ilu na ha li eyi, ti a npè ni: Pipe-ẹwà, Ayọ̀ gbogbo ilẹ aiye!

Ka pipe ipin Ẹk. Jer 2

Wo Ẹk. Jer 2:15 ni o tọ