Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹk. Jer 2:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

BAWO li Oluwa ti fi awọsanma bo ọmọbinrin Sioni ni ibinu rẹ̀! ti o sọ ẹwa Israeli kalẹ lati oke ọrun wá si ilẹ, ti kò si ranti apoti-itisẹ rẹ̀ li ọjọ ibinu rẹ̀!

Ka pipe ipin Ẹk. Jer 2

Wo Ẹk. Jer 2:1 ni o tọ