Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deu 14:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ọmọ Lefi, nitoriti kò ní ipín tabi iní pẹlu rẹ, ati alejò, ati alainibaba, ati opó, ti mbẹ ninu ibode rẹ, yio wá, nwọn o si jẹ nwọn o si yó; ki OLUWA Ọlọrun rẹ ki o le bukún ọ ninu gbogbo iṣẹ ọwọ́ rẹ ti iwọ nṣe.

Ka pipe ipin Deu 14

Wo Deu 14:29 ni o tọ