Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 9:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi si gbadura si Oluwa Ọlọrun mi, mo si ṣe ijẹwọ mi, mo si wipe, Oluwa, iwọ Ọlọrun ti o tobi, ti o si li ẹ̀ru, ti npa majẹmu ati ãnu mọ́ fun awọn ti o fẹ ẹ, ati fun awọn ti o pa ofin rẹ̀ mọ́;

Ka pipe ipin Dan 9

Wo Dan 9:4 ni o tọ