Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 9:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhin ọ̀sẹ mejilelọgọta na li a o ke Ẹni-ororo na kuro, kì yio si si ẹnikan fun u, ati awọn enia ọmọ-alade kan ti yio wá ni yio pa ilu na ati ibi-mimọ́ run; opin ẹniti mbọ yio dabi ikún omi, ati ogun titi de opin, eyi ni ipari idahoro.

Ka pipe ipin Dan 9

Wo Dan 9:26 ni o tọ