Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 8:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si gbé oju mi soke, mo si ri, si kiye si i, àgbo kan ti o ni iwo meji duro lẹba odò na: iwo mejeji na si ga, ṣugbọn ekini ga jù ekeji lọ, eyiti o ga jù li o jade kẹhin.

Ka pipe ipin Dan 8

Wo Dan 8:3 ni o tọ