Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 8:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati nipa arekereke rẹ̀ yio si mu ki iṣẹ ẹ̀tan ṣe dẽde lọwọ rẹ̀; on o si gbé ara rẹ̀ ga li ọkàn rẹ̀, lojiji ni yio si pa ọ̀pọlọpọ run, yio dide si olori awọn ọmọ-alade nì; ṣugbọn on o ṣẹ́ laisi ọwọ.

Ka pipe ipin Dan 8

Wo Dan 8:25 ni o tọ