Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 8:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wipe, kiyesi i, emi o mu ọ mọ̀ ohun ti yio ṣe ni igba ikẹhin ibinu na: nitoripe, akokò igba ikẹhin ni eyi iṣe.

Ka pipe ipin Dan 8

Wo Dan 8:19 ni o tọ