Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 8:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃li o si wá sibi ti mo duro: nigbati o si de, ẹ̀ru bà mi, mo si da oju mi bolẹ: ṣugbọn o wi fun mi pe, Kiyesi i, ọmọ enia: nitoripe ti akokò igba ikẹhin ni iran na iṣe.

Ka pipe ipin Dan 8

Wo Dan 8:17 ni o tọ