Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 8:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe ti emi, ani emi Danieli si ti ri iran na, ti mo si nfẹ imọ̀ idi rẹ̀, si kiyesi i, ẹnikan duro niwaju mi, gẹgẹ bi aworan ọkunrin.

Ka pipe ipin Dan 8

Wo Dan 8:15 ni o tọ