Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 7:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Titi de ihinyi li opin ọ̀ran na. Bi o ṣe ti emi Danieli ni, igbero inu mi dãmu mi gidigidi, oju mi si yipada lori mi: ṣugbọn mo pa ọran na mọ́ li ọkàn mi.

Ka pipe ipin Dan 7

Wo Dan 7:28 ni o tọ