Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 7:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

A si fi agbara ijọba fun u, ati ogo, ati ijọba, ki gbogbo enia, ati orilẹ, ati ède, ki o le ma sìn i; agbara ijọba rẹ̀ si jẹ agbara ijọba ainipẹkun, eyiti a kì yio rekọja, ati ijọba rẹ̀, eyiti a kì yio le parun.

Ka pipe ipin Dan 7

Wo Dan 7:14 ni o tọ