Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 7:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

LI ọdun kini Belṣassari, ọba Babeli, ni Danieli lá alá, ati iran ori rẹ̀ lori akete rẹ̀: nigbana ni o kọwe alá na, o si sọ gbogbo ọ̀rọ na.

Ka pipe ipin Dan 7

Wo Dan 7:1 ni o tọ