Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 6:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun mi ti ran angeli rẹ̀, o si dì awọn kiniun na lẹnu, ti nwọn kò fi le pa mi lara: gẹgẹ bi a ti ri mi lailẹṣẹ niwaju rẹ̀; ati niwaju rẹ pẹlu, ọba, emi kò si ṣe ohun buburu kan.

Ka pipe ipin Dan 6

Wo Dan 6:22 ni o tọ