Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 6:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si sunmọ iho na o fi ohùnrére ẹkun kigbe si Danieli: ọba dahùn o si wi fun Danieli pe, Danieli! iranṣẹ Ọlọrun alãye! Ọlọrun rẹ, ẹniti iwọ nsìn laisimi, ha le gbà ọ lọwọ awọn kiniun bi?

Ka pipe ipin Dan 6

Wo Dan 6:20 ni o tọ