Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 4:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni wakati kanna ni nkan na si ṣẹ si Nebukadnessari, a si le e kuro larin enia, o si jẹ koriko bi malu, a si mu ki ìri ọrun sẹ̀ si i lara, titi irun ori rẹ̀ fi kún gẹgẹ bi iyẹ idì, ẽkana rẹ̀ si dabi ti ẹiyẹ.

Ka pipe ipin Dan 4

Wo Dan 4:33 ni o tọ