Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 11:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ni ipò rẹ̀, yio ma bu ọlá fun ọlọrun awọn ilu olodi, ani ọlọrun kan ti awọn baba rẹ̀ kò mọ̀ ri ni yio ma fi wura, ati fadaka, ati okuta iyebiye, ati ohun daradara bu ọlá fun.

Ka pipe ipin Dan 11

Wo Dan 11:38 ni o tọ