Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 11:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhin eyi, yio kọ oju rẹ̀ si erekuṣu wọnni, yio si gbà ọ̀pọlọpọ: ṣugbọn balogun kan fun ara rẹ̀, yio fi opin si ẹ̀gan rẹ̀: ati nipò eyi, yio mu ẹ̀gan rẹ̀ pada wá sori ara rẹ̀.

Ka pipe ipin Dan 11

Wo Dan 11:18 ni o tọ