Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dan 1:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si fi Jehoiakimu, ọba Juda le e lọwọ, pẹlu apakan ohun-elo ile Ọlọrun, ti o kó lọ si ilẹ Ṣinari, si ile oriṣa rẹ̀: o si kó ohun-elo na wá sinu ile-iṣura oriṣa rẹ̀.

Ka pipe ipin Dan 1

Wo Dan 1:2 ni o tọ