Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amo 9:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, ọjọ na de, li Oluwa wi, ti ẹniti ntulẹ yio le ẹniti nkorè bá, ati ẹniti o ntẹ̀ eso àjara yio le ẹniti o nfunrùgbin bá; awọn oke-nla yio si kán ọti-waini didùn silẹ, gbogbo oke kékèké yio si di yiyọ́.

Ka pipe ipin Amo 9

Wo Amo 9:13 ni o tọ