Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 9:44 Yorùbá Bibeli (YCE)

Abimeleki, ati ẹgbẹ́ ti o wà lọdọ rẹ̀ sure siwaju, nwọn si duro li ẹnu-ọ̀na ibode ilu na: ẹgbẹ meji si sure si gbogbo awọn enia na ti o wà ninu oko, nwọn si kọlù wọn.

Ka pipe ipin A. Oni 9

Wo A. Oni 9:44 ni o tọ