Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 9:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn arakunrin iya rẹ̀ si sọ gbogbo ọ̀rọ wọnyi nitori rẹ̀ li etí gbogbo awọn ọkunrin Ṣekemu: àiya wọn si tẹ̀ si ti Abimeleki; nitori nwọn wipe, Arakunrin wa ni iṣe.

Ka pipe ipin A. Oni 9

Wo A. Oni 9:3 ni o tọ