Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 9:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gaali ọmọ Ebedi si wipe, Tani Abimeleki? ta si ni Ṣekemu, ti awa o fi ma sìn i? Ṣe ọmọ Jerubbaali ni iṣe? ati Sebulu ijoye rẹ̀? ẹ mã sìn awọn ọkunrin Hamoru baba Ṣekemu: ṣugbọn nitori kili awa o ha ṣe ma sìn on?

Ka pipe ipin A. Oni 9

Wo A. Oni 9:28 ni o tọ