Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 8:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gideoni si wi fun wọn pe, Emi o bère nkan lọwọ nyin, pe ki olukuluku nyin ki o le fi oruka-etí ti mbẹ ninu ikogun rẹ̀ fun mi. (Nitoriti nwọn ní oruka-etí ti wurà, nitoripe ọmọ Iṣmaeli ni nwọn iṣe.)

Ka pipe ipin A. Oni 8

Wo A. Oni 8:24 ni o tọ