Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 7:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si mú meji ninu awọn ọmọ-alade Midiani, Orebu ati Seebu; Orebu ni nwọn si pa lori apata Orebu, ati Seebu ni nwọn si pa ni ibi-ifọnti Seebu, nwọn si lepa awọn ara Midiani, nwọn si mú ori Orebu ati Seebu wá fi fun Gideoni li apa keji odò Jordani.

Ka pipe ipin A. Oni 7

Wo A. Oni 7:25 ni o tọ