Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 4:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si ranṣẹ pè Baraki ọmọ Abinoamu lati Kedeṣi-naftali jade wá, o si wi fun u pe, OLUWA, Ọlọrun Israeli kò ha ti paṣẹ pe, Lọ sunmọ òke Tabori, ki o si mú ẹgba marun ọkunrin ninu awọn ọmọ Naftali, ati ninu awọn ọmọ Sebuluni pẹlu rẹ.

Ka pipe ipin A. Oni 4

Wo A. Oni 4:6 ni o tọ