Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 3:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati o dé, o fọn ipè ni ilẹ òke Efraimu, awọn ọmọ Israeli si bá a sọkalẹ lọ lati òke na wá, on si wà niwaju wọn.

Ka pipe ipin A. Oni 3

Wo A. Oni 3:27 ni o tọ