Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 3:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn on tikara rẹ̀ pada lati ibi ere finfin ti o wà leti Gilgali, o si wipe, Ọba, mo lí ọ̀rọ ìkọkọ kan ibá ọ sọ. On si wipe, Ẹ dakẹ. Gbogbo awọn ẹniti o duro tì i si jade kuro lọdọ rẹ̀.

Ka pipe ipin A. Oni 3

Wo A. Oni 3:19 ni o tọ