Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 20:48 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọkunrin Israeli si pada tọ̀ awọn ọmọ Benjamini, nwọn si fi oju idà kọlù gbogbo ilu, ati ẹran, ati ohun gbogbo ti nwọn ní: gbogbo ilu ti nwọn ri ni nwọn fi iná kun pẹlu.

Ka pipe ipin A. Oni 20

Wo A. Oni 20:48 ni o tọ