Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 20:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina, nwọn pẹhinda niwaju awọn ọkunrin Israeli si ọ̀na ijù; ṣugbọn ogun na lepa wọn kikan; ati awọn ti o ti ilu wọnni jade wá ni nwọn pa lãrin wọn.

Ka pipe ipin A. Oni 20

Wo A. Oni 20:42 ni o tọ