Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 20:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn ọkunrin Israeli si pẹhinda ni ibi ìja na, Benjamini si bẹ̀rẹsi kọlù ninu awọn ọkunrin Israeli, o si pa bi ọgbọ̀n enia: nitoriti nwọn wipe, Nitõtọ a lù wọn bolẹ niwaju wa, gẹgẹ bi ìja iṣaju.

Ka pipe ipin A. Oni 20

Wo A. Oni 20:39 ni o tọ