Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 20:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si kọlù Benjamini niwaju Israeli: awọn ọmọ Israeli si pa ẹgba mejila ọkunrin o le ẹdẹgbẹfa li ọjọ́ na ninu awọn enia Benjamini: gbogbo awọn wọnyi li o kọ́ idà.

Ka pipe ipin A. Oni 20

Wo A. Oni 20:35 ni o tọ