Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 20:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni gbogbo awọn ọmọ Israeli, ati gbogbo awọn enia na gòke lọ, nwọn wá si Beti-eli, nwọn sọkun, nwọn si joko nibẹ̀ niwaju OLUWA, nwọn si gbàwẹ li ọjọ́ na titi di aṣalẹ; nwọn si ru ẹbọ sisun ati ẹbọ alafia niwaju OLUWA.

Ka pipe ipin A. Oni 20

Wo A. Oni 20:26 ni o tọ