Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

A. Oni 20:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awa o si mú ọkunrin mẹwa ninu ọgọrun jalẹ ni gbogbo awọn ẹ̀ya Israeli, ati ọgọrun ninu ẹgbẹrun, ati ẹgbẹrun ninu ẹgbãrun, lati mú onjẹ fun awọn enia na wá, ki nwọn ki o le ṣe, nigbati nwọn ba dé Gibea ti Benjamini, gẹgẹ bi gbogbo ìwa-wère ti nwọn hù ni Israeli.

Ka pipe ipin A. Oni 20

Wo A. Oni 20:10 ni o tọ